Enquiries: +2348073528899, 09168692180 || support@fulfillmentict.com
HYMN 1
1.Okan ha wa t’o kun fun ‘oro,
Ti aye re' kun f’aniyan?
Gbe oro re wa sodo Jesu
Fi gbogbo aniyan sile n’ibe.
Refrain
Gb’awon aniyan at’edun re
Wa s’ib ’ite aanu I’odo Re;
Ko s’eru t'Oluwa ko le ru,
Ko si ore bii Jesu.
2. Ko s’oluranlowo bii ti Re’;
Ko s’elomii' t’o sunmo wa,
Ko s’ibomii’ t’a le k'eru Io,
Ko s’elomii' t’o n gbo adura.
3. Wa nisinsinyi, ma se lora;
Gbo ohun ipe aanu Re;
Wa, ma se beru ohunkohun
Wo, yoo r'isinmi n’ib’ite aanu.
HYMN 2
1. Gbo Olugbala n pe awon t’eru n pa,
"Eyin ti n i e, e wa gba isinmi;
Wa, e ma duro pe, N o ru eru yin,
Gbe iyonu ati aniyan re wa.
Refrain
Wa s’odo Mi, N o fun yin n’isinmi,
Gb’ajaga Mi s’orun; gbo t’Emi k’o ye,
Onirele ni Mi, Oniwa - pele
Ajaga Mi rorun, Eru Mi fuye'”.
2.Ibanuje ha ti bori okan re?
Idaamu ha ti m’okan re rewesi?
Awon iwa ese ha n yo o I’enu?
Gbe e to Jesu wa, Yoo fun o n’isinmi.
3. Oro aye yii ha bo okan re,
Oro ni osan ati ni oru;
Ese aimodi ha n te o lori ba?
Olugbala n pe o pe - "Wa s’odo Mi.”
4. O ha n e aniyan lori i e re.
At’igbe-aye re, pelu ‘reti re?
Eru ’dalebi ha w’okan re I'orun?
Wa sodo Jesu, Yoo fun o n’isinmi.
5. Idanwo ha ti n egun okan re bi?
Wahala aye ha ti bi o subu?
Oluwa yoo so okan re di mimo,
Yoo fisinmi fun o n’nu Emi Mimo.
To get the complete hymn (full version), kindly click here now